ABUL FATHI FORUM

ABUL FATHI FORUM

Share

This thread is for lovers of nature when it comes to health and other areas of our lives.

06/03/2023

Every thing is Easy when you are Crazy about it; And nothing is Easy when you are Lazy about it.

05/04/2022

Copied....
Ẹni tó bá n bá olórí burúkú ènìyàn rìn,
olóriire enìyàn yio máa sá fún-un.
Àì lè sọ̀rọ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ oríburúkú. Ènìyàn mẹ́ta n run ọbẹ̀, ẹni kínní ní wón n kó ọbẹ̀ yìí púpọ̀, ẹni kejì ní, èmi náà tí fẹ́ sọ bẹ́ẹ̀ Ó yẹ kí ẹni kẹta ó le mọ̀ wípé òun ni wọ́n n báwí, àì tètè sọ̀rọ̀ rẹ̀ ló kó báa.
Ẹni tí wọ́n ní orí rẹ̀ burú, tó tún n f'ọ́wọ raá.
Ẹyẹlé tó gbórí kékeré wáyé inú ilé ló n gbé.
Ẹyẹ àgbìgbò to gbé orí nlá wáyé inú igbó l’òun wà.
Tí orí ájá bá fẹ́ burú, ètùtù ogún bíbọ á yà sí olówó rẹ̀.
Bí orí ìgalà bá sì fẹ́ gbàbọ̀dè, nínú igbó, yíó ṣeré lọ ìbí tí kiniun tọ̀ sí.
Ejò tó ṣeré lọ ojúde ìjàlọ, o ti ṣi òde lọ.
Èkúté tó wọ ilé ológbò, ó ti ṣi ilé wọ̀
Ọjọ́ tí alágbàro bá ṣi oko gbà, ló n gba oko oní wèrèpè.
Agbọ́kànlé rẹ kò níí d’òfo. Orí rẹ kò níí burú, lasẹ Èdùmàrè.

03/04/2022

Inú bí ẹ̀fúùfùlẹ̀lẹ̀, ó wó igi lu omi,
Inú bí omi, ó gbé igi lọ. Ìbínú kò mọ̀ pé, olówó òun kò l’ẹ́sẹ̀ n’ílẹ̀. Ìbínú ló n múni yọ idà nínú àkọ̀, ìtìjú ló n múni bẹ́ẹ. Ẹni tí inú n bí tó fa àdá yọ, tó bẹ́ ọmọlakejì rẹ̀ lórí, ṣé tí inú rẹ̀ bá rọ̀, ṣé yíó dá ori míràn padà s’ọ́rùn rẹ̀ ni. Inú àbíjù máa n jékí ire ènìyàn o jìnnà síi ni. Inú ló bí bàbá,tó sọ fún ọmọ rẹ wípé, òun o kìí ṣe ẹgbẹ́ rẹ̀, bi kò ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ, gbogbo ayé ló mọ̀ pé, kékeré kọ́ ní bàbá fi ju ọmọ rẹ̀ lọ. àbọ̀ omi tó n da olówó rẹ̀ láàmú. Inú burúkú ní oogùn òṣì. Ìpọ̀nrí Aláṣọ méjì tó n ránṣẹ sí onípààrọ̀, ọgbọ́n àti rin hòòhò, ló n dá. Ẹni bá tí n bínú jù, kò má ṣiṣẹ́ mọ́,
torípé, isẹ́ tí o fi ojú ọwọ́ ṣe, ẹyìn ọwọ́ ní yíó fi dáa nù. Lóòtó ọmọ alè ènìyàn ló n rínú ti kii bi. Ṣùgbón, inú àbíjù, wèrè lo n sọni dà. Ìwà jẹ́jẹ́ pẹlu sùúrù la lè fi lo ilé ayé ni ìrọ̀rùn.
Inú buruku kò ní bí ọ. O kò níí f'ọwọ́ ara rẹ ṣe ara rẹ lasẹ Èdùmàrè. A kú isinmi oni.

30/01/2022

BODE THOMAS....

21/04/2020

This thread is for lovers of nature when it comes to health and other areas of our lives.

22/08/2019

Work, Worship & Wait

The 3 simple steps that can help you achieve success are Work, Worship and Wait. “Work” as if everything depends on you, “Worship” as if everything depends on God, and “Wait” knowing that it’s going to happen. Don’t lose patience! A combination of work, worship and wait is an absolute guarantee of success.

Anybody who uses the formula of faith and toil backed by patience cannot just fail because this is a magic formula that many successful people have used to make their dreams come true.

Do you want to succeed? Then, check these 3 steps: Do you really work? Do you worship? And do you have the patience to wait? If you are following these 3 steps religiously, then there is no way you can stop, and you’re absolutely going to achieve success in a short time!

26/04/2018

Prayers are invisible,
but they make impossible
things possible.
It is Allah’s
job to work the wonders.
Our part is simply to pray.

28/02/2018

We All Have Dreams.
But In Order To Make Dreams
Come Into Reality,
It Takes An Awful Lot Of
Determination, Dedication, Self-discipline.

27/08/2017

etu ibon ojulowo Aolo kunna dada, aodasi inu epo pupa aomafi Je Ibepe dudu.

♍️♍️
Ewe renren
Eru alamo
aose papo pelu omi, aoma mu niyen ojoojuma
♈️♈️♈️
Epo Ira igbo Aolo Ti yiodi powder ao mix e papo ma aoma fi omi tutu Lo ni igba gbogbo
♑️♑️♑️♑️
Horo inu Eso pear
Aowa ti yioto mefa abi jubelo Aolo kunna dada, aosagbe, aobu Oyin gidi si, aoma mu ni sibi meji meji laro Losan lale.

28/07/2017

A you're not only a wonderful person but a great friend. Its a blessing to have both of them in you.
Thanks for making home the loveliest place on earth.
Wish you a very Happy Jumuhat

Want your school to be the top-listed School/college in Offa?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Website

Address


Offa