Scripturist001
EDUTAINER//GRAMMAR COACH//ORATOR//POET//EDUCATOR//PROOFREADER//JOURNALIST//SCRIPTURIST
❤️
Ẹ bá wa sọ́ fún atóbitán kó ṣe jẹ́jẹ́
Ayé gba jẹ́jẹ́, ayé gba pẹ̀lẹ́, ayé gba ẹ̀rọ̀ pẹ̀sẹ̀.
Ẹ sọ fún àwọn tí wọ́ní àwọn làwọ́n lòní pé àwọn kọ́ ló lọ̀la. Toriwipe wípé arúgbó s'oge rí, èkísà náà lo ìgbà tirè, ìgbà a máa gbani; ìgbà a máa pani, ìgbà a máa yẹni, ìgbà asì máa yeni. Bí èyàn bá wùwà àìdáa lá lọ, kí ó rántí wípé àbọ̀ ń bọ̀ wá bọ̀. Àgbé jẹun yó tán, ó fọ́ akèrègbè, ó ti gbàgbé pé ìgbà òùngbẹ sì ń bọ̀. Ẹjẹ ka gb'ayé se réré. Ìgbà làá ló, ẹni kan olèé lo ayé gbo. Baa pẹ láyè aaditan, bi ao ba pẹ laye naa aaditan, gbogbo ntì abase lónì ìtàn nio di lọla...
Oriyomi Hamzat Live
09/06/2026
May God, in His infinite mercy, ensure that the voices of the people of Oyo are heard, and may Alhaji Oriyomi Hamzat emerge to become the next governor of Oyo State. 🤲🤲🤲
Religion X-rayed: What religion is not? This is a must-watch!
By Ridwan Ayanfe Olanrewaju (Scripturist)
Un-happy Children’s Day!
This is my greeting from Oyo State, I know you understand. 😢
Oriyomi Hamzat Live is who we want accordingly. 👍💯❤️
Oriyomi Hamzat Live is the People's choice!
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the establishment
Telephone
Website
Address
Iree
Osogbo