Asejere

Asejere

Share

A Yoruba Newspaper that promotes entrepreneurs and focuses on the informal sector, particularly the market women and men, artisan, traders, etc.

Ìlera Eko ṣàgbékalẹ̀ eto tuntun fawọn ẹgbẹ alafọwọsowọpọ - Àṣejèrè 29/03/2025

https://www.asejere.net/ilera-eko-%e1%b9%a3agbekale-eto-tuntun-fawon-egbe-alafowosowopo/

Ìlera Eko ṣàgbékalẹ̀ eto tuntun fawọn ẹgbẹ alafọwọsowọpọ - Àṣejèrè Lori eto ati ri daju pe tonile talejo ipinlẹ Eko lo wa ni ilera to peye, ìjọba ipinlẹ Eko labẹ iṣakoso gomina Babajide Sanwo-Olu pẹlu ajọ toun moju to eto ilera nipinlẹ naa iyẹn ajọ Lagos State Health Management Agency, LASHMA, ti ṣe to “Ilera N’Tiwa to jẹ ẹgbẹ alaj....

Asiko yii lo yẹ kawa ọmọ Yoruba ṣatilẹyin fun Tinubu, o gbọdọ lọ lẹẹkan si i - Bamigboye - Àṣejèrè 29/03/2025

https://www.asejere.net/asiko-yii-lo-ye-kawa-omo-yoruba-%e1%b9%a3atileyin-fun-tinubu-o-gbodo-lo-leekan-si-i-bamigboye/

Asiko yii lo yẹ kawa ọmọ Yoruba ṣatilẹyin fun Tinubu, o gbọdọ lọ lẹẹkan si i - Bamigboye - Àṣejèrè …Irin ajo oṣelu o rọrun rara, ẹẹmẹta ni mo dije sile aṣofin Eko   Lara awọn ijọba ibilẹ to ti pẹ lorile-ede Naijiria nijọba ibilẹ Mushin, awọn alaga to ti jẹ tẹlẹ nibẹ si ṣe daadaa ṣugbọn ara ọtọ ni ti Ọnarebu Emmanuel Bamigboye to n ṣakoso kansu na...

Gomina Ademọla Adeleke naa ti joye Aṣiwaju - Àṣejèrè 14/05/2024

https://www.asejere.net/gomina-ademola-adeleke-naa-ti-joye-aṣiwaju/

Gomina Ademọla Adeleke naa ti joye Aṣiwaju - Àṣejèrè Gbogbo eto lo ti to bayii lati fi Gomina ipinlẹ Ọṣun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke, jẹ Aṣiwaju ilu Ẹdẹ, lọjọ Aje, Mọnde, ọjọ Aje, ọjọ kẹtala, oṣu Karun-un ọdun yii. Ifijoye yii lo ṣe wẹku pẹlu ayẹyẹ ọjọọbi ọdun kẹrinlelọgọta ti Adeleke dele a...

Wọn ni Toyin Abraham fi Funkẹ Akindele ṣe yẹyẹ nitori awọọdu - Àṣejèrè 14/05/2024

https://www.asejere.net/won-ni-toyin-abraham-fi-funke-akindele-ṣe-yeye-nitori-awoodu/

Wọn ni Toyin Abraham fi Funkẹ Akindele ṣe yẹyẹ nitori awọọdu - Àṣejèrè Ohun tawon omo ori ero ayelujara n so bayii ni pe Toyin Abraham n fi Funke Akindele se yeye nitori bi fiimu Funke se fidi remi lopin ose to koja yii. Kehinde Bankole lo gba awoodu fiimu to dara ju lodun naa, bo tie je pe fiimu Funke Akindele lo pawo wole julo. Se ni […]

Fiimu Funkẹ Akindele fidi rẹmi, ṣugbọn jagunjagun, Iya Rainbow gba awọọdu AMVCA - Àṣejèrè 14/05/2024

https://www.asejere.net/fiimu-funke-akindele-fidi-remi-ṣugbon-jagunjagun-iya-rainbow-gba-awoodu-amvca/

Fiimu Funkẹ Akindele fidi rẹmi, ṣugbọn jagunjagun, Iya Rainbow gba awọọdu AMVCA - Àṣejèrè Bo ti ya gbajumo osere tiata nni, Funke Akindele ti gbogbo eeyan n pe ni Jenifa lenu pe o fidi remi, lawon ololufe re naa n yanu pe fiimu re, Tribe Called Judah ko gba awoodu kan kan nibi idije AMVCA to waye lopin ose to koja yii. Idije naa je eleeekewa iru re, to […]

Ajọ NFF ṣafihan Finidi George, kooṣi tuntun fun Super Eagles - Àṣejèrè 14/05/2024

https://www.asejere.net/ajo-nff-ṣafihan-finidi-george-kooṣi-tuntun-fun-super-eagles/

Ajọ NFF ṣafihan Finidi George, kooṣi tuntun fun Super Eagles - Àṣejèrè Ajo to n sakoso egbe agbaboolu nile wa, NFF ti se afihan akonimoongba tuntun fun egbe agbaboolu ile wa, Super Eagles. Eni naa ni Finidi George. Bee o ba gbagbe, Finidi George ni igbakeji fun koosi Jose Peseiro, otyinbo to ko egbe naa lo si idije ile Afrika to waye laipe yii. Ilu Abuja ni […]

Gomina kede ẹdinwo fawọn lanlọọdu atawọn difẹlọpa - Àṣejèrè 14/05/2024

https://www.asejere.net/gomina-kede-edinwo-fawon-lanloodu-atawon-difelopa/

Gomina kede ẹdinwo fawọn lanlọọdu atawọn difẹlọpa - Àṣejèrè Lati mu edinku ba awon ile to n fojoojumo wo nipinle Eko, ijoba ti din owo ti awon lanloodu leto ati san funjoba lori ati gba awon iwe ase ijoba lori ile won. Ko seni to letoo ati kole ipinle Eko la i je pe won gba iwe ase ijoba lati ko iru ile bee, […]

E wo iye tileeṣẹ Yinka Fọlawiyọ pa wọle f'Eko lori epo rọbi - Àṣejèrè 14/05/2024

https://www.asejere.net/e-wo-iye-tileeṣe-yinka-folawiyo-pa-wole-feko-lori-epo-robi/

E wo iye tileeṣẹ Yinka Fọlawiyọ pa wọle f'Eko lori epo rọbi - Àṣejèrè Iroyin ti te wa lowo pe ogorun milionu naira lo din ninu bilionu merin naira (N3.911bn) ninu iye owo ti ipinle Eko ti pa wole lori ida metala owo to ye ki won maa gba lori epo robi. Bee o ba gbagbe, odun 2016 nipinle Eko darapo mo awon ipinle ti won n gba lowo […]

Sanwo-Olu fẹẹ bẹrẹ ajọṣepọ nla pẹlu awọn alapata l'Ekoo - Àṣejèrè 14/05/2024

https://www.asejere.net/sanwo-olu-fee-bere-ajoṣepo-nla-pelu-awon-alapata-lekoo/

Sanwo-Olu fẹẹ bẹrẹ ajọṣepọ nla pẹlu awọn alapata l'Ekoo - Àṣejèrè Gomina ipinle Eko maa bere ajosepo nla kan pelu awon alapata atawon eleran nipinle Eko, iso eran to wa ni Oko Oba ni Agege ni eto naa ti maa bere, bee ni won si tun maa sefilole awon ibuso ti won a ti maa ta eran naa. Eto yii waye lati toju awon eran ti […]

Ofin to maa fiya jẹ awọn to n wa yanrin lọna aitọ maa jade laipẹ - Alebioṣu - Àṣejèrè 14/05/2024

https://www.asejere.net/ofin-to-maa-fiya-je-awon-to-n-wa-yanrin-lona-aito-maa-jade-laipe-alebioṣu/

Ofin to maa fiya jẹ awọn to n wa yanrin lọna aitọ maa jade laipẹ - Alebioṣu - Àṣejèrè Ijoba ipinle Eko n se eto lowo lati fofin de awon to n wa yanri lona aito latinu osa nipinle naa. Komisanna to bojuto idagbasoke awon etido nipinle naa, iyen Minisitry of Waterfront Infrastructure Development (MWID), Onarebu Yacoob Ekundayo Alebiosu, ti gbogbo eeyan mo si Dayo Bush lo soro yii di mi...

Want your business to be the top-listed Media Company in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Address


Lagos
23401