Yeye Agbasaga

Yeye Agbasaga

Share

Official Yeye Agbasaga page. We're live on here every first Thursday of the month, 5pm-6pm. Join Us!

04/12/2025
Photos from Yeye Agbasaga's post 15/12/2024

Gbajumo lafo More a gbe wa o
Mo dupe fun aseyori inawo wa ni December 1 2024 olorun ti fi anu gba gbogbo gbajumo lafo ope ni fun olodunmare πŸ’ƒπŸΌπŸ’ƒπŸΌπŸ’ƒπŸΌπŸ’ƒπŸΌπŸ’ƒπŸΌ

01/09/2024

Happy birthday to you my son easy one Israel Oladokun long life and prosperity πŸŽ‚πŸΏπŸ¦πŸŽ‰ igba Odun Odun kan ninu Owo Omo alafia emi gigun pelu ifokan bale lolorun ma fi jiki e o amin πŸ™

08/07/2024

Gbajumo lafo More a gbe wa o
Mo gba ladura fun gbogbo omo Afo nile loko ati ni okere abo olorun a dajun lori gbogbo wa ati idile enikankan wa olorun a bawa dawo iku ojiji duro ni ilu wa
Gbogbo ogun tole ma da erun ati lo si ilu abinibi wa ba wa olorun a bawa se gbogbo e lase wole
Ominale afo a gbeja gbogbo omo afo lowo awon arogo bogo je
Gbogbo wa la ma ranu gba lagbara olorun oba amin More a gbe wa oo

04/07/2024

Iku doro iku seka iku mu eni wa lo egbo wa ebi wa omoiya wa ore wa oloye pataki nilu Afo iku o ma seka oo Chief Josiah Oni Olowu Asiwaju ti ilu Afo jade layie huuuu😭😭😭
Gbogbo omo bibi ilu Afo a ku ara fera ku o gbogbo ebi Olowu ati ebi chief Bada e ku ara fera ku o awayie maku kosi gbogbo wa la je gbese iku
Pogodo omo Afo e joni fowo so owo po dajudaju a se gbogbo ogun to nja wa ni ilu wa e joo e ma joni gbagbe ile oo atunse Afo o dowo gbogbo wa
Gbajumo lafo more a gbe gbogbo wa oo

Want your business to be the top-listed Media Company in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Website

Address


Lagos