Astrogel

Astrogel

Share

Astrogel, owned by cloudangel is a place to explore Astrology and Life,a place to seek astrological g

04/04/2022

FEB 19 TO MARCH 20 ( PISCES )
irawo yi Eya Omi ni,ti awon oni imo irawo npe ni PISCES
🗣hmmm Astrology so wipe Awon ti abi si Abe irawo yi je enito ni Aanu OMOLAKEJI loju, eyiti won koni fe ki awon o maa ri OMOLAKEJI won ninu inira tori won ki ri Araa gbe si to bege,titi won yoo fi yo iru eni bee kuro ninu inira re,opo eniyan yio si maa Saaba fi Oju Oloore won gungi, nigbati won ti mo wipe Alaanu Samaria ni won,won je eniti nmaa nduro tini ni Ojo isoro,pupo ninu awon ti abi ni Abe irawo yi aaye ododo ati aaye eniti a lee fi Okan tan ni won maa nsaa ba wa ni Opo igba, sugbon die ninu won je oni imo taraeni nikan(egocentric) awon OBIRIN won je enito ni ataa(careless house keeping)nibi itoju ile,nitori aifi Okan ara won bale,won gbudo je eniti yio ni Igboya (caurage) ki Owo(hand) won le baa te ohunrere laye,won je enito ni agbaja Oro siso pupo, eyiti won yio si feran lati maa beere awon ibeere orisirisi lowo eniti Oro bajo dawonpo,esi ti abaa si fun won,won yio diimu sinsin ni,eyi ti o soro fun won lati gbagbe, awon ti abi ni Abe irawo yi je eniti OLOHUN OBA Saaba fun ni Ewa(pretty) pupo,Adufe sini won je pelu, sugbon won gbudo maa se atunse Lori Oro siso pupo won,ati oniran nran ibeere won pelu,tori o lee je ki awon eniyan o maa se ILARA won.
Bakanna,won feran lati maa fi idi Oro ododo mule pelu awon isesi won wonyin, sugbon ti won bati npa iro,lesekese ni ao ti mo, nigbati won baa ti npa ara Oro kanna ni eemeji tabi eemeta,tabi ti won bati nkalolo.

FAVORITES COLORS
(1)Green.
(2)Blue.
(3)Yellow.
(4)pink.
(5)white.

IKILO PATAKI:- Okunrin won gbodo Sora fun ISEKUSE tori wipe OBIRIN maa nda IRIN AJO won ru pupo Tori wipe won nma nife si ALE yiyan.

EEWO FUN PIECES:-
(1)Won ko gbodo yaa Bata ti ki nse tiwon woo,won o si gbudo gba ki enikeni ti ese bo bata won.
(2)Won ko gbodo maa rin ni aiwobata.
(3)Won ko gbodo mu Oti (alcohol)
(4)Won ko gbodo lo oogun oloro tabi mu igbo,tabi awon oogun ti won fi oogun oloro po,fun apeere (India h**p cocaine,or any narcotic substances).
(5)Won ko gbodo je OKETE.
(6)Won kogbodo ma je Eja-Aro
(7)Won kogbodo je ila
(8)Awon obirin ti abi si Abe irawo yi kogbodo ko Oko (husband),tori tobalo,tobabo won ma nje ika abamo. re sile.
(9)Ki awon obirin ti abi si Abe irawo gbinyanju lati se ise Oko (husband) Orun ati ibujoko,kiwon le ni ifokanbale ninu ile Oko (husband) won.

Ti won bati se ikan ninu awon nkan EEWO yi,ki won gbinyanju lati lo nkan ti yio pa gbogbo Oro EEWO na ninu Ara won, kiwon le lo igbesi Aiye to rorun laiye won,tori o lewu tiwon ba mu oju to EEWO na.

ISE TI AYAN MO WON:-
(1)Actor or Actress.
(2) Artist.
(3)Chiropodist.
(4)Hospital worker
(5)Photographer.
(6)Priest.
(7)Prison worker.
(8)Sailor, Spiritual healer.
(9) Writer
(10)Musician.
(11)Doctor or Nurse.
(12) Marine related
(13) chemical petroleum oils.
(14)Lawyer
(15)Architect.
(16)Travel Agent

Ti o baa fe mo nipa akosejaye re (to know your life path interpretation) call or whatpp me on this number

08134910320 or 09011692599

Bami so wipe ORI INU MI KONI BAA TODE MI JE

02/11/2020

Ask AN Astrologer Send a message to learn more

20/07/2020

ASTRONEWS by Astrogel.
VALIDITY: LAST WEEK IN JULY, 2020.

1. Some Countries and cities will experience a big disaster by flood which will cause ruins to buildings,houses and farmlands, affect transportation and communications system.

2. A scientific breakthrough in technology , possibly on finance and commerce will be achieved. However,as good as it is, consequent problems will affectthe commercial, financial , communication or transportation system.


The news above as of the time of writing, aren't a cumulation of what had happened, but a predictive news from an astrological perspective.

Common tags.

18/07/2020

18/07/2020
18/07/2020

16/07/2020

Check out your sun sign .

Want your business to be the top-listed Business in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Address


Www. Facebook. Com/astrogel
Lagos

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00