Broda Fire
David Adeniji - Fire
ADURA ATI IDANILẸKỌ 🔥
Ẹdarapọ Mọ WhatsApp
Channel Adura Wa Bayi
👇👇👇👇👇👇👇
https://whatsapp.com/channel/0029VbAs4hL7tkjA6iaZ9h34
WHATSAPP: 09037290514 (Broda Fire)
Iwọ Ti Oòni Fi Ọwọ́ Rẹ Gbe Oku Ọmọ Si Ninu Ọdún Yìí, Bami Fi Ìgbàgbọ Se AMIN Adura Yìí
24/06/2026
Ọlọrun Fi Opin Sí Ipade Ibí Ti Àwọn Òkùnkùn Nṣe Lori Ọrọ Ayé Rẹ Lóni Lorukọ Jésù Kristi Oluwa...
Fi Ìgbàgbọ Se AMIN Adura Yìí. Kìo Fi Ranṣẹ Si Group Adura Miran...
23/06/2026
Lorukọ Jesu kristi Oluwa, Ọlọrun Fi Ina Àti Ara Le Àwọn Ẹmi Okunkun Ipọnju Àti Inira Kuro Láraarẹ. Itusilẹ De Baọ 🙏🙏🙏🔥
22/06/2026
Mo Gba Adura Fún Gbogbo Abiyamọn To Ri AMIN Adura Yíì Se. Ọta Koni Sọ Ọmọ Rẹ Dì Were Ọsan Gangan Lorukọ Jésù Kristi 🙏
21/06/2026
Iwọ Tíó Ri AMIN Adura Yìí Se, Aye Koni Fi Posi Daọ Lọla Lojiji. Iku Òjìji Koni Wọle Rẹ.
20/06/2026
Ọkọ Rẹ Koni Ri Àkóbá Nibi Isẹ. Aye Koni Dì Ẹru Ọran Le Ọkọ Rẹ Lóri Lorukọ Jésù Kristi...
Fi Adura Yíì Ransẹ Si Ọkọ Rẹ Bayii 🙏🙏
19/06/2026
Iwọ Tio Gbagbọ Wípe Ikú Ọmọ Koni Jẹ Tiẹ T**i Lailai, Se AMIN Sí Adura Yìí Pẹlu Ìgbàgbọ Bayi....
Oòni Foju Sunkún Ọmọ Laye Lorukọ Jésù... Gbogbo Àwọn To Tì Sẹlẹ Síi, Wọn Koni Ri Iruẹ Mọn Lágbára Ọlọrun Ọba.🙏🙏🙏
(Fi Adura Yìí Ranṣẹ Sí Group Adura Mẹta)
Ẹ DARAPỌ MỌN ADURA WA BAYI LORI WHATSAPP: +2348069755971
ỌLỌRUN A DÁÀBÒ RẸ BO YIN TẸBITARA LOJU ORUN YIN LONI LORUKỌ JESU KRISTI
18/06/2026
Iwọ Àti Ẹbi Rẹ, Ẹoni Jẹ Majele Lorukọ Jésù
Aye Koni Gba Ibí Ounjẹ Mú Iwọ Ati Ọmọ Rẹ.....
Ẹ Darapọ Mọn WhatsApp Adura Wà Bayi: 0806 975 5971
IRE AYỌ YIN A DE, ẸONI MỌN IBANUJẸ LORUKỌ JESU
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Website
Address
Ilesa