ALAWIYE Blog
A ki yin kaabo s'ori a'pere ti o n gbaruku ti idagbasoke Asa ati Ise ede Yoruba. Alawiyeblog !!!
08/05/2026
Gẹ́gẹ́ bó ṣe sọ, gbogbo ǹkan ti ń padà bọ̀ sípò ní Nàìjìríà láti ìgbà tí ìsejọba Ààrẹ Bola Tinubu ti bẹ̀rẹ̀
Kí ni èrò yin ??
27/04/2026
Sùúrù lọba ìwà
Àgbà tó ní sùúrù,
Ohun gbogbo ló ní.
Bí a tí ń lọ nínú ọ̀sẹ̀ tuntun yìí,
Ẹ jẹ́ ká kọ́ sùrúù.
Ká fẹ̀lẹ̀ sọ̀rọ̀ nígbà tí inú ń bí wa,
Ká fi ẹ̀lẹ̀ gbọ́rọ̀,
Ká sì tún to fèsì.
Ká ní ọjọ́ rere ooo
26/04/2026
A kú ìsinmi oo
Kí ni gẹ̀ẹ́sì Olùgbèjà?
25/04/2026
A kú dédé ìwòyí, láàrin Ìtẹ̀lẹ̀- Yekin àti Rotimi Salami, ta ni ó se eré Lover Boy jù?
23/04/2026
Àwọn Ọba aládé láti àwọn ìpínlẹ̀ káàkàkiri nì orílẹ èdè Nàíjírà péjú sí ibi àpérò tí Gómìnà Fabura se kòkárí ẹ ní ìpínlẹ̀ Port Harcourt.
Ọ̀ọ̀ni ifẹ̀ ni ó jẹ́ alága ìpàdé náà gẹ́gẹ́ bí alága àwọn Ọba ní apá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn lọ́balọ́ba ni ó péjú síbẹ̀ láti ilẹ̀ káàrọ́ọ̀ o jìí í re bíi Olubadan of Ibadan, Deji of Akure, Olowo of Owo, Oniru of Iruland, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.
Àmọ́ sá, Aláàfin ìlú ọ̀yọ́ kò sí ní ìkàlẹ̀. Kíni ẹ̀yin rò pé ó ò fá tí aláàfin kò fi sí ní ìkàlẹ̀?
22/04/2026
Bosenlọ
Ìpàdé Ìjọba ìpílẹ̀ Ọ̀yọ́ tí Gómínà Seyi Makinde síwájú rè ti buwọ́ lu owó tó tó bílíọ̀nù mẹ́fà náírà ó dín díẹ́- (5.813 bilion naira) fún àwọn tí ó dín ẹgbẹrún ó dín ní ọgọ́rùn-ún ènìyàn tí ilé àti dúkiá wọn farakásá ọ̀nà tí wọ́n ńse lọ́wọ́- (circular road)
Gẹ́gẹ́ bíi kọmisọ́nnà fún ìkéde, Prince Dotun Oyelade, àwọn tí ọrọ ọ̀hún kàn yoo ní aǹfàní láti gba owó náà láìpẹ́.
22/04/2026
Gómínà Ipínlẹ̀ ọ̀sun ti gùn lé àti yan àwọn ìgbìmọ̀ ìpolongo ìbò ìyànpada sípò lọ́la òde òní.
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Telephone
Address
Beere, Mapo
Ibadan