IFE OKAN MI.

IFE OKAN MI.

Share

:@AKINWALE OSUNMAKIN ADOLA . IFE OKAN MI �THIS MY LOVE � HEART ��

04/12/2021

Bo o ba n fe eni kan sibe ti ko si lokan e lati fi se oko tabi aya, nse lo da bi omode to n fi bebi sere, amo to wabi ju u si nigba to ya. Iyen si ni lati mo boya awon mejeeji a le bara won kale bi won ba gbera won niyawo! Olorun a fi emi suru si mi ninu ati emi suru si okan mi Amin! Gbadura yi fun ara re! Olorun eledare mi mo' be o ni ikeyin ojo aiye mi, Olorun mu emi de ijoba re ijoba Olorun Amin

04/12/2021

Opo iwadii tawon eeyan se ti fi han pe awon to segbeyawo lai tii pe Omo ogun odun(20) saba maa n kora won sile laarin igba die ti won ba fera won! Bo o ba ti wa lo leni to o fe nigba to o si wa "igba itanna ododo ewe," Looto, iyen le maa je nnkan babara loju awon ojugba re, tori pupo ninu won lo maa n fe tete mo bi ibalopo se n ri lara! A mo, o le mu iru ironu yen kuro lokan, ko o si fiyen ju won lo! Bibeli saa gba e niyanju pe ko o "sa fun agbere ROOMU 12:2, Bibeli so wipe, nitori agbere ki olukuluku ki o ni oko tabi aya, 1korinti 7:2-3 Ki oko ki o ma se ohun ti o ye si aya: be gege si li aya pelu si oko! Gbadura si Olorun eledare, Olorun maje n si oko fe! Olorun ma so mi ki abo Olorun ki odaju lori mi Amin

01/12/2021

Mase se iyemeji lori eniti ohun fe! Gbadura fun oko re ololufe re ni ojo owuro kutukutu! Adara fun o Amin!

01/12/2021

Jowo ma' se si mi gbo! Yan Ololufe kan laayo! O ni si ile wo Amin!

30/10/2021

Ba ololufe re soro itunu, inu re adun si e

21/08/2021

You are welcome my dear friends

Photos from IFE OKAN MI.'s post 10/01/2021

👄💑Ma se ro pe o maa leele leni ti waa fe. 2 Ka sooto , 💏igba to o ba tii leni to o n fe gan-an lo maa lominira to Po ju lati 'yo ni igba ewe re.💑 3 Igba yen gan-an lo si maa raye tun iwa e se, ti waa si le mu ki 💪👫 ajose re pelu ololufe re 💏 dan moran si i 👣👋

10/01/2021

💏💑👫Bo ba n wu e lati leni ti waa maa fe sona nigba ti ko tii ya e lati segbeyawo, nse lo maa da bi igba to o fe fi agidi sedanwo asekagba ile eko girama nigba to o si wa nileewe alakoobere. 2 O daju pe iyen o daa to. O di dandan ko o waye lati mo awon eko ti won n koni nile eko girama, ko o le mo ohun to o maa ba pade ninu idanwo ohun. 💏3 Boran fifera eni sona se ri gan-an niyen. 4 Ba a se so loke, fifera eni sona ki i se oran ere. Tori naa ko o to torun bo o, o ni lati mo eko Pataki kan daaju, iyen beeyan se n bani doree👭.5 Bo o ba si wa reni to te e lorun, waa le mo bo o se le maa se si i, ke e le dore ara yin. 6 👫 O se tan, bi tokotaya ba je ore ara won , igbeyawo won a dun bi oyin. Ki Oluwa ran wa lowo 🙏🙏🙏 Omo Adola👄👋

Photos from IFE OKAN MI.'s post 13/10/2020

😎😂SE ENIKENI NI MO LE FE. Gbogbo bata ko lo le ba e lese mu, bee naa si ni gbogbo awon to o n ba pade o le je oko tabi aya rere e. Ko o baa le dahun ibeere to gbeyin yen, fara bale ronu nipa eni to o ni lokan lati fe. Amo ko o sora o, Ko ma lo je pe ohun to o fe ri nikan ni waa maa ri. Tori naa, fara e bale. Gbiyanju lati mowa eni naa daadaa. Iyen si maa beere pe ko o sapa gidigidi. Ko ye kiyen ya e lenu da o. Apeere kan ree, Je ka so pe o fe ra oko ayokele kan. Nje o o ni ye oko ayokele naa wo daadaa. Abi bo ba daa ti daa loju, o pari naa niyen. Nje ko ni bogbon mu pe ko o ye e wo tinu teyin, ko o si tun wo bi enjinni e se n sise si paapaa. Wiwa eni teeyan maa fe gbege ju rira oko ayokele lo. Sibe, oju lasan lopo awon to n wa eni ti won maa fe n wo. O maa n ya won lara lati so ohun ti won jo feran. ADOLA😇😍

27/09/2020

O maa n nira fawon baba atawon mama kan lati fife han sawon Omo won tori awon obi tiwon naa o fi ojulowo IFE han si won. 2 Gbogbo igba ni momi maa n jagbe mo mi temi naa si maa n gbo won lenu, Amo ni bayii, mo ti n gbiyanju lati fawon imoran inu Oro Olorun silo. O si wulo fun mi. Momi ti n yiwa pa da bayii. Imoran won ti mo n fi silo ti wa je ki n loye Momi daadaa. Oro wa ti wo gidi gan-an bayii.

12/09/2020

To o ba fe mura sile de igba to o maa bere si fe eni kan sona tabi to o maa segbeyawo, ka iwe Mimo 2peteru 1:5-7, ko o si fokan si animo kan to ye ko o sise le lori. Leyin osu kan, sayewo bo o se mo animo yen to lati bo se han niun iwa e si.

09/08/2020

Je ki tebi-tore ran e lowo.

Want your business to be the top-listed Media Company in Ibadan?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Telephone

Address


Challenge
Ibadan