Emiola Ismaila one
I AM NATIVE DOCTOR & HERBERLIST
24/08/2024
Ebe ASINA
Ako Pepeye kan aopa aola laya Aofi eye kowe kan si ninu aoko ata ijosi si ninu aowa gbe sinu ape aoko ewe AJEOBALE ojoo le Lori Aofi atare 3 le Lori aojo aolo aoro sinu Ike funfun aomafi ogi tabi oti tabi custard lo laro tabi alale
Aseje ebe awon agba
Ewe ati egbo AJEOBALE,,ati ewe ati egbo ORIJIN ,, ataijosi die aolo papo aofise eyele funfun kan ti agesi 16, lepo niyo aoje pelu adura
Hmmmmm oga ooo
Aseje asina
Awo EKUN die ,,obe kan ,,oga gbigbe ibile kan ,,1000 new note,,ataijosi ______ aolopo aofise Ori ogunfe kan aogesi 9 or 7 aose lepo niyo aokoje a*o tobadara ni aowo je
31/05/2024
Ose asina ,,eye kowe kan,,oga gbigbe kan aogun tiyodi powder ewe ajeobale tutu,, ewe sawerepepe,,ewe tangiri, aogun mose aoko sinu igba onikoko aomawe laro laro
31/05/2024
Akisa logba ri Kosi inkan tolo t**i
29/05/2024
Order for your self
WhatsApp 07036491297
Ose eyonu ,, igbin apinu kan,,ewe ajeobale tutu,,ewe orijin,,epo obo aogun mose aoko sinu Ike funfun aomawe laro laro
Hello everyone
01/05/2024
Happy new month
Hello
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the practice
Telephone
Website
Address
Moniya
Ibadan