NTA OYO
News and Current Affairs, Information, Education, Entertainment, Sports,
OJO AWON OSISE NI ILU OYO
Awon osise kakiri orileede Naijiria n se ayeye Ojo awon osise odun yii Pelu ipe tuntun fun imugbooro itoju won , abojuto to lagbara fun ago ara won ,awon nilu Oyo Naa ko si gbeyin.
Akori ayeye odun yii tio Je Aabo ati ilera ninu ayipada oju Ojo tun n fa akiyesi pataki fun awon ilana to daabo bo awon osise kuro ninu ewu ayika.
ONIROYIN WA FUNKE AMOLE WA NiBE
WORKERS DAY IN OYO TOWN .
Workers across Nigeria are marking this year’s Workers’ Day with renewed calls for improved welfare, better working conditions, and stronger protection of labour rights, and workers in Oyo Town are not left out.
This year’s celebration, themed “Safety and Health in a Changing Climate,” is also drawing attention to the urgent need for policies that will safeguard workers against emerging environmental and occupational hazards.
The report...
92nd BIRTHDAY CELEBRATION OF SURVEYOR BENJAMIN ADEBIMPE LALA.
Tributes have continued to pour in for the 92-year-old nonagenarian, Surveyor Benjamin Adebimpe Lala, as family members, friends, and and associates as well as well-wishers celebrate his remarkable life and enduring legacy.
The event, held in a serene and joyous atmosphere, attracted dignitaries and guests from all walks of life to honour the celebrant.
NTA Oyo news crew captured the moment.
AWON AKANDA EDA KOPA NINU IDANWO POST UTME JAMB ODUN YI.
Laika awon Ipenija ara ati ifarapa Opolo si, awon akeko akanda eda tikopa ninu idanwo POST UTME 2026 ti n lo Lowolowo, tI JOINT ADMISSIONS AND MATRICULATION BOARD Se to.
Awon oluko idanwo naa Fi igboya , Ifarapa Ati ipinu han bi won Se darapo mo ogoro awon oluko idanwo kaakiri orileede, ninu Ilepa won lati tesiwaju si eko Giga.
ONIROYIN WA FUNKE AMOLE WA NiBE EJE KA GBO SIWAJU.
SPECIAL NEEDS CANDIDATES WRITE 2026 POST UTME/JAMB
Despite physical and sensory challenges, candidates physically challenged have taken part in the ongoing 2026 Unified Tertiary Matriculation Examination conducted by the Joint Admissions and Matriculation Board,JAMB.
The candidates displayed courage, determination, and resilience as they joined millions of other candidates nationwide in the pursuit of higher education programmes.
Our correspondent filed in this report.
AYEYE ISINKU OLOGBE AYANNIYI AKINADE
Amoran ti lo S**o awon onigbagbo lati ba olorun won laja ki won si gba Jesus ni oluwa Ati olugbala won ,bi a Se sin Oku akikanju kan Akinade Ayanniyi si Ilu Oyo.
Ikilo yi ni Aare ijo onitebomi Tilu Oyo Benjamin Tella , Se lasiko Isinku ti won Se ni ijo onitebomi isokun, Oyo.
Funke Amole ni oniroyin
REMAINS OF AKINADE AYANNIYI LAID TO REST
Christians have been urged to embrace total reconciliation with God and accept Jesus Christ as their Lord and Saviour as the remains of an icon, Akinade Ayanniyi, was laid to rest in Oyo Town.
The charge was given by the President of the Oyo Baptist Conference, Benjamin Tella, during the funeral service held at Isokun Baptist Church Oyo.
The Report.
AYEYE ODUN AJINDE NILU OYO
Alaafin Oyo, Oba Abimbola Akeem Owoade ti pe awon kristeni lati fara mo awon Ilana irubo ati
aimotara-eni- nikan , ki won si yago fun ese, ki won si tesiwaju ni mimu awon eko pipe ti Jesu Kristi lori agbelebu.
Oro yi lowaye nIbi ayeye odun Ajinde eyi to waye ni Galilee nilu Oyo.
Funke Amole wa nibe, eje ka gbo siwaju.
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Oyo
211215