Enitan Emmanuel

Enitan Emmanuel

Share

Superior evangelist, prophet of god.send ur prayer request to my page

25/07/2020

GBOGBO OGUN TI AWON EGBON IDILE BABA MI NGBE NITORI OGO NLA MI,TI WON PERA WON NI PHARAOH, TI KOPADA LEHIN MI, MOPALASE NI ORUKO JESU,KI AGBARA WON SEGBE SINU OKUN PUPA,

25/07/2020

GBOGBO,ALAGBARA IDILE BABA,TO NI KIN FONI SHO.PE NIBO NI MOFE GBEGBA,TIO NFI AIYE NI MI LARA.KI AWON OGUN ORUN BAMI FI IDA INA PAWON RE PATAPATA.NI ORUKO JESU.

24/07/2020

GBOGBO AGBARA OGUN IDILE BÀBA TO NI IWO KONI DE IBI IRE-AYORE,NINU ODUN YI,NI ORUKO JESU,AGBARA OGUN NA KO GBINA DANU.FUN IWO TI OBA RI AMIN META SE,WA WONU OGO NLA RE LO.

Want your place of worship to be the top-listed Place Of Worship in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Website

Address

Lagos